28 Nígbà tí Dafidi rí i pé OLUWA ti gbọ́ adura rẹ̀ ní ibi ìpakà Onani ará Jebusi, ó bẹ̀rẹ̀ sí rú àwọn ẹbọ rẹ̀ níbẹ̀.
Ka pipe ipin Kronika Kinni 21
Wo Kronika Kinni 21:28 ni o tọ