29 Títí di àkókò yìí, àgọ́ OLUWA tí Mose pa ní aṣálẹ̀, ati pẹpẹ ẹbọ sísun wà ní ibi pẹpẹ ìrúbọ ní Gibeoni.
Ka pipe ipin Kronika Kinni 21
Wo Kronika Kinni 21:29 ni o tọ