6 Dafidi bá pe Solomoni, ọmọ rẹ̀, ó pàṣẹ fún un pé kí ó kọ́ ilé kan fún OLUWA Ọlọrun Israẹli.
Ka pipe ipin Kronika Kinni 22
Wo Kronika Kinni 22:6 ni o tọ