Kronika Kinni 23:3 BM

3 Ó ka gbogbo àwọn Lefi tí wọ́n jẹ́ ọkunrin tí wọ́n dàgbà tó ọmọ ọgbọ̀n ọdún sókè, gbogbo wọn jẹ́ ẹgbaa mọkandinlogun (38,000).

Ka pipe ipin Kronika Kinni 23

Wo Kronika Kinni 23:3 ni o tọ