Kronika Kinni 25:2 BM

2 Lára àwọn ọmọ Asafu wọ́n yan Sakuri, Josẹfu, Netanaya, ati Asarela; wọ́n wà lábẹ́ àkóso Asafu, wọn a sì máa sọ àsọtẹ́lẹ̀ lábẹ́ àkóso ọba.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 25

Wo Kronika Kinni 25:2 ni o tọ