10 Hosa, láti inú ìran Merari bí ọmọkunrin mẹrin: Ṣimiri (ni baba rẹ̀ fi ṣe olórí, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé kì í ṣe òun ni àkọ́bí);
Ka pipe ipin Kronika Kinni 26
Wo Kronika Kinni 26:10 ni o tọ