Kronika Kinni 5:23 BM

23 Ìdajì ẹ̀yà Manase ń gbé Baṣani, wọ́n pọ̀ pupọ; wọ́n tàn ká títí dé Baali Herimoni, Seniri, ati òkè Herimoni.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 5

Wo Kronika Kinni 5:23 ni o tọ