Kronika Kinni 9:26 BM

26 Nítorí àwọn olórí mẹrin wọnyi, tí wọ́n jẹ́ ọmọ Lefi, ni wọ́n tún ń ṣe alabojuto àwọn yàrá tẹmpili ati àwọn ilé ìṣúra tí ó wà ninu ilé Ọlọrun.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 9

Wo Kronika Kinni 9:26 ni o tọ