Kronika Kinni 9:27 BM

27 Wọ́n ń gbé àyíká ilé Ọlọrun, nítorí iṣẹ́ wọn ni láti máa bojútó o, ati láti máa ṣí ìlẹ̀kùn rẹ̀ ní àràárọ̀.

Ka pipe ipin Kronika Kinni 9

Wo Kronika Kinni 9:27 ni o tọ