2. Kro 1:1 YCE

1 A si mu Solomoni, ọmọ Dafidi, lagbara lori ijọba rẹ̀, Oluwa Ọlọrun rẹ̀ si wà pẹlu rẹ̀, o si gbé e ga gidigidi.

Ka pipe ipin 2. Kro 1

Wo 2. Kro 1:1 ni o tọ