2. Kro 12:3 YCE

3 Pẹlu ẹgbẹfa kẹkẹ́, ati ọkẹ́ mẹta ẹlẹṣin: awọn enia ti o ba a ti Egipti wá kò niye; awọn ara Libia, awọn ara Sukki, ati awọn ara Etiopia.

Ka pipe ipin 2. Kro 12

Wo 2. Kro 12:3 ni o tọ