2. Kro 14:1 YCE

1 Bẹ̃ni Abijah sùn pẹlu awọn baba rẹ̀, nwọn si sìn i ni ilu Dafidi: Asa ọmọ rẹ̀ si jọba ni ipò rẹ̀. Li ọjọ rẹ̀, ilẹ na wà li alafia li ọdun mẹwa.

Ka pipe ipin 2. Kro 14

Wo 2. Kro 14:1 ni o tọ