2. Kro 14:3 YCE

3 Nitori ti o mu pẹpẹ awọn ajeji oriṣa kuro, ati ibi giga wọnni, o si wó awọn ere palẹ, o si bẹ ere-oriṣa wọn lulẹ:

Ka pipe ipin 2. Kro 14

Wo 2. Kro 14:3 ni o tọ