2. Kro 15:5 YCE

5 Ati li ọjọ wọnni alafia kò si fun ẹniti o njade, tabi fun ẹniti nwọle, ṣugbọn ibanujẹ pupọ li o wà lori gbogbo awọn olugbe ilẹ wọnni.

Ka pipe ipin 2. Kro 15

Wo 2. Kro 15:5 ni o tọ