2. Kro 18:25 YCE

25 Nigbana ni ọba Israeli wipe, Ẹ mu Mikaiah, ki ẹ si mu u pada sọdọ Amoni, olori ilu, ati sọdọ Joaṣi, ọmọ ọba.

Ka pipe ipin 2. Kro 18

Wo 2. Kro 18:25 ni o tọ