2. Kro 19:4 YCE

4 Jehoṣafati si ngbe Jerusalemu: o nlọ, o mbọ̀ lãrin awọn enia lati Beerṣeba de òke Efraimu, o si mu wọn pada sọdọ Oluwa, Ọlọrun awọn baba wọn.

Ka pipe ipin 2. Kro 19

Wo 2. Kro 19:4 ni o tọ