2. Kro 2:11 YCE

11 Nigbana ni Huramu, ọba Tire, kọwe dahùn o si ranṣẹ si Solomoni pe, Nitori ti Oluwa fẹran awọn enia rẹ̀ li o ṣe fi ọ jọba lori wọn.

Ka pipe ipin 2. Kro 2

Wo 2. Kro 2:11 ni o tọ