2. Kro 2:18 YCE

18 O si yàn ẹgbã marundilogoji ninu wọn lati ru ẹrù, ati ọkẹ mẹrin lati ṣe aké-okuta li ori òke, ati egbejidilogun alabojuto lati kó awọn enia ṣiṣẹ.

Ka pipe ipin 2. Kro 2

Wo 2. Kro 2:18 ni o tọ