2. Kro 21:4 YCE

4 Nigbati Jehoramu si dide si ijọba baba rẹ̀, o mu ara rẹ̀ le, o si fi idà pa gbogbo awọn arakunrin rẹ̀, ati ninu awọn ijoye Israeli.

Ka pipe ipin 2. Kro 21

Wo 2. Kro 21:4 ni o tọ