2. Kro 22:10 YCE

10 Ṣugbọn nigbati Ataliah, iya Ahasiah, ri pe ọmọ on kú, o dide o si run gbogbo iru ọmọ ijọba ile Judah.

Ka pipe ipin 2. Kro 22

Wo 2. Kro 22:10 ni o tọ