2. Kro 24:24 YCE

24 Nitori ogun awọn ara Siria dé pẹlu ẹgbẹ diẹ, Oluwa si fi ogun ti o pọ̀ gidigidi le wọn lọwọ, nitoriti nwọn kọ̀ Oluwa, Ọlọrun awọn baba wọn silẹ. Bẹ̃ni nwọn si ṣe idajọ Joaṣi.

Ka pipe ipin 2. Kro 24

Wo 2. Kro 24:24 ni o tọ