2. Kro 24:7 YCE

7 Nitori Ataliah, obinrin buburu nì ati awọn ọmọ rẹ ti fọ ile Ọlọrun; ati pẹlu gbogbo ohun mimọ́ ile Oluwa ni nwọn fi ṣe ìsin fun Baalimu.

Ka pipe ipin 2. Kro 24

Wo 2. Kro 24:7 ni o tọ