2. Kro 25:10 YCE

10 Nigbana li Amasiah yà wọn, ani ẹgbẹ-ogun ti o ti tọ̀ ọ lati Efraimu wá, lati tun pada lọ ile wọn: ibinu wọn si ru gidigidi si Juda, nwọn si pada si ile wọn ni irunu.

Ka pipe ipin 2. Kro 25

Wo 2. Kro 25:10 ni o tọ