2. Kro 26:19 YCE

19 Nigbana ni Ussiah binu, awo-turari si mbẹ lọwọ rẹ̀ lati sun turari: ati nigbati o binu si awọn alufa, ẹ̀tẹ yọ ni iwaju rẹ̀, loju awọn alufa ni ile Oluwa lẹba pẹpẹ turari.

Ka pipe ipin 2. Kro 26

Wo 2. Kro 26:19 ni o tọ