2. Kro 27:2 YCE

2 O si ṣe eyiti o tọ́ li oju Oluwa, gẹgẹ bi gbogbo eyiti baba rẹ̀ Ussiah ti ṣe; kiki kò wọ inu tempili Oluwa lọ, ṣugbọn awọn enia nṣe ibi sibẹsibẹ.

Ka pipe ipin 2. Kro 27

Wo 2. Kro 27:2 ni o tọ