2. Kro 28:24 YCE

24 Ahasi si kó gbogbo ohun-elo ile Ọlọrun jọ, o si ké kuro lara ohun-elo ile Ọlọrun, o si tì ilẹkun ile Oluwa, o si tẹ́ pẹpẹ fun ara rẹ̀ ni gbogbo igun Jerusalemu.

Ka pipe ipin 2. Kro 28

Wo 2. Kro 28:24 ni o tọ