2. Kro 29:15 YCE

15 Nwọn si kó awọn arakunrin wọn jọ, nwọn si yà ara wọn si mimọ́, nwọn si wá nipa aṣẹ ọba gẹgẹ bi ọ̀rọ Oluwa, lati gbá ile Oluwa mọ́.

Ka pipe ipin 2. Kro 29

Wo 2. Kro 29:15 ni o tọ