2. Kro 29:29 YCE

29 Nigbati nwọn si ṣe ipari ẹbọ riru, ọba ati gbogbo awọn ti o wà pẹlu rẹ̀ tẹ̀ ara wọn ba, nwọn si sìn.

Ka pipe ipin 2. Kro 29

Wo 2. Kro 29:29 ni o tọ