2. Kro 29:9 YCE

9 Sa wò o, awọn baba wa ti ti ipa idà ṣubu, ati awọn ọmọkunrin wa, ati awọn ọmọbinrin wa, ati awọn obinrin wa wà ni igbekun nitori eyi.

Ka pipe ipin 2. Kro 29

Wo 2. Kro 29:9 ni o tọ