2. Kro 31:16 YCE

16 Laika awọn ọkunrin, ti a kọ sinu iwe idile, lati ọmọ ọdun mẹta ati jù bẹ̃ lọ, fun olukuluku wọn ti o nwọ̀ inu ile Oluwa lọ, ìwọn tirẹ̀ lojojumọ, fun iṣẹ ìsin wọn, ninu ilana wọn, gẹgẹ bi ipa wọn;

Ka pipe ipin 2. Kro 31

Wo 2. Kro 31:16 ni o tọ