2. Kro 32:1 YCE

1 LẸHIN ti a ti ṣe iṣẹ wọnyi lotitọ, Sennakeribu, ọba Assiria, de, o si wọ̀ inu Juda lọ, o si dótì awọn ilu olodi, o si rò lati gbà wọn fun ara rẹ̀.

Ka pipe ipin 2. Kro 32

Wo 2. Kro 32:1 ni o tọ