2. Kro 32:32 YCE

32 Ati iyokù iṣe Hesekiah ati iṣẹ rere rẹ̀, kiyesi i, a kọ wọn sinu iwe iran Isaiah woli, ọmọ Amosi, ani ninu iwe awọn ọba Juda ati Israeli.

Ka pipe ipin 2. Kro 32

Wo 2. Kro 32:32 ni o tọ