2. Kro 32:5 YCE

5 O mu ara rẹ̀ le pẹlu, o si mọ gbogbo odi ti o ti ya, o si gbé e ga de awọn ile-iṣọ, ati odi miran lode, o si tun Millo ṣe ni ilu Dafidi, o si ṣe ọ̀kọ ati apata li ọ̀pọlọpọ.

Ka pipe ipin 2. Kro 32

Wo 2. Kro 32:5 ni o tọ