2. Kro 32:8 YCE

8 Apa ẹran-ara li o pẹlu rẹ̀, ṣugbọn Oluwa Ọlọrun wa li o pẹlu wa lati ràn wa lọwọ, ati lati jà ogun wa. Awọn enia na si gbẹkẹ wọn le ọ̀rọ Hesekiah, ọba Juda.

Ka pipe ipin 2. Kro 32

Wo 2. Kro 32:8 ni o tọ