2. Kro 33:15 YCE

15 O si kó awọn àjeji ọlọrun ati ere kuro ni ile Oluwa, ati gbogbo pẹpẹ ti o ti tẹ́ lori òke ile Oluwa ati ni Jerusalemu, o si kó wọn danu kuro ni ilu.

Ka pipe ipin 2. Kro 33

Wo 2. Kro 33:15 ni o tọ