2. Kro 34:24 YCE

24 Bayi li Oluwa wi, Kiyesi i, emi o mu ibi wá si ihinyi ati si awọn ti ngbe ibẹ na, ani gbogbo egún ti a kọ sinu iwe ti nwọn ti kà niwaju ọba Juda:

Ka pipe ipin 2. Kro 34

Wo 2. Kro 34:24 ni o tọ