2. Kro 34:32 YCE

32 O si mu ki gbogbo awọn ti o wà ni Jerusalemu ati Benjamini duro ninu rẹ̀, awọn ti ngbe Jerusalemu si ṣe gẹgẹ bi majẹmu Ọlọrun, Ọlọrun awọn baba wọn.

Ka pipe ipin 2. Kro 34

Wo 2. Kro 34:32 ni o tọ