2. Kro 35:13 YCE

13 Nwọn si fi iná sun irekọja na gẹgẹ bi ilana na: ṣugbọn awọn ẹbọ mimọ́ iyokù ni nwọn bọ̀ ninu ìkoko, ati ninu òdu ati ninu agbada, nwọn si pin i kankan fun gbogbo enia.

Ka pipe ipin 2. Kro 35

Wo 2. Kro 35:13 ni o tọ