2. Kro 36:1 YCE

1 NIGBANA ni awọn enia ilẹ na mu Jehoahasi, ọmọ Josiah, nwọn si fi i jọba ni ipò baba rẹ̀ ni Jerusalemu.

Ka pipe ipin 2. Kro 36

Wo 2. Kro 36:1 ni o tọ