2 O si ṣe agbada didà nla, igbọnwọ mẹwa lati eti kan de eti ekeji, o ṣe birikiti, igbọnwọ marun si ni giga rẹ̀; okùn ọgbọ̀n igbọ̀nwọ li o si yi i kakiri:
Ka pipe ipin 2. Kro 4
Wo 2. Kro 4:2 ni o tọ