2. Kro 6:39 YCE

39 Ki iwọ ki o gbọ́ adura wọn ati ẹ̀bẹ wọn lati ọrun wá, ani lati ibugbe rẹ wá, ki o si mu ọ̀ran wọn duro, ki o si dari ẹ̀ṣẹ awọn enia rẹ jì ti nwọn ti da si ọ.

Ka pipe ipin 2. Kro 6

Wo 2. Kro 6:39 ni o tọ