2. Kro 7:18 YCE

18 Nigbana ni emi o fi idi itẹ ijọba rẹ múlẹ̀, gẹgẹ bi emi ti ba Dafidi, baba rẹ dá majẹmu, wipe, a kì yio fẹ ẹnikan kù fun ọ ti yio ma ṣe akoso ni Israeli.

Ka pipe ipin 2. Kro 7

Wo 2. Kro 7:18 ni o tọ