15 Nwọn kò si yà kuro ninu ilana ọba nipa ti awọn alufa, ati awọn ọmọ Lefi niti olukuluku ọ̀ran, ati niti iṣura.
Ka pipe ipin 2. Kro 8
Wo 2. Kro 8:15 ni o tọ