2. Kro 9:6 YCE

6 Ṣugbọn emi kò gba ọ̀rọ wọn gbọ́, titi mo fi de, ti oju mi si ti ri i; si kiyesi i, a kò rò idaji titobi ọgbọ́n rẹ fun mi; nitori ti iwọ kọja òkiki ti mo ti gbọ́.

Ka pipe ipin 2. Kro 9

Wo 2. Kro 9:6 ni o tọ