Owe 11:3 YCE

3 Otitọ aduro-ṣinṣin ni yio ma tọ́ wọn; ṣugbọn arekereke awọn olurekọja ni yio pa wọn run.

Ka pipe ipin Owe 11

Wo Owe 11:3 ni o tọ