Owe 11:4 YCE

4 Ọrọ̀ kì ini anfani li ọjọ ibinu: ṣugbọn ododo ni igbani lọwọ ikú.

Ka pipe ipin Owe 11

Wo Owe 11:4 ni o tọ