Owe 13:3 YCE

3 Ẹniti o pa ẹnu rẹ̀ mọ́, o pa ẹmi rẹ̀ mọ́; ṣugbọn ẹniti o ṣi ète rẹ̀ pupọ yio ni iparun.

Ka pipe ipin Owe 13

Wo Owe 13:3 ni o tọ