Owe 13:4 YCE

4 Ọkàn ọlẹ nfẹ, kò si ri nkan; ṣugbọn ọkàn awọn alãpọn li a o mu sanra.

Ka pipe ipin Owe 13

Wo Owe 13:4 ni o tọ