Owe 28:25 YCE

25 Ẹniti o ṣe agberaga li aiya, a rú ìja soke, ṣugbọn ẹniti o gbẹkẹ rẹ̀ le Oluwa li a o mu sanra.

Ka pipe ipin Owe 28

Wo Owe 28:25 ni o tọ