26 Ẹniti o gbẹkẹ le aiya ara rẹ̀, aṣiwère ni; ṣugbọn ẹnikẹni ti o ba nfi ọgbọ́n rìn, on li a o gbà la.
Ka pipe ipin Owe 28
Wo Owe 28:26 ni o tọ